top of page
Yorùbá
O máa nilo Adobe Reader lati wo àwọn ìwé-pélébé wọ̀nyí. Ṣe ìgbàsílẹ̀ Adobe Reader ọ̀fẹ́ níbí ní tí o kọ̀ bá ni.
A kò gbà ọ́ ní ìmọ̀ràn lati tẹ àwọn ìwé-pélébé wọ̀nyí jade lati ojú òpo wẹ́ẹ̀bù tí o bá nlo PDF Reader tí ó yàtọ̀ sí Adobe Acrobat Reader. Ṣe ìgbàsílẹ̀ wọn sí ẹ̀rọ rẹ, kí o tó tẹ̀ wọ́n jade.
*A kò gbà ẹnikẹ́ni láàyè láti ṣàkọsílẹ̀, ṣàtúndá, ṣàtúnṣe, tàbí kí o ta àwọn ìwé-pélébé wa ní ọ̀nàkanà. Ṣíṣe àwọn ǹkan bayi túmọ̀ sí wipé o njà wá lólè e ohun-ìní ọgbọ́n wa
Àwọn Ìwé-pélébé tí ó wà
Tẹ ìwé-pélébé aláwọ̀ s'órí ìwé funfun; Tẹ ìwé-pélébé funfun s'órí ìwé t'óní àwọ̀.
bottom of page